Welcome to Yoruba Indigenes Foundation
Eku abo sibujoko ojulowo asa omo Yoruba. Nibiti e de yi, a yio fi toyin leti bi asa ati ise Yoruba ti dara to, awon eya eyiti won ni irepo, iwa tutu bi adaba , eto oro aje to ye koro ati ise ona. Ogbeni Olumide Aderibole da Egbe Omo-Bibi Yoruba sile gegebi oti se je logun lati gbe asa ati ise awa omo Kaaro ojire.